Isaiah 19:20

Isaiah 19:20 YCB

Yóò sì jẹ́ ààmì àti ẹ̀rí sí OLúWA àwọn ọmọ-ogun ní ilẹ̀ Ejibiti. Nígbà tí wọ́n bá ké pe OLúWA nítorí àwọn aninilára wọn, yóò rán olùgbàlà àti olùgbèjà kan sí wọn tí yóò sì gbà wọ́n sílẹ̀.