Isaiah 25:8

Isaiah 25:8 YCB

Òun yóò sì gbé ikú mì títí láé. OLúWA Olódùmarè yóò sì nu gbogbo omijé nù, kúrò ní ojú gbogbo wọn; Òun yóò sì mú ẹ̀gàn àwọn ènìyàn rẹ̀ kúrò ní gbogbo ilẹ̀ ayé. OLúWA ni ó ti sọ ọ́.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Isaiah 25:8

Isaiah 25:8 - Òun yóò sì gbé ikú mì títí láé.
OLúWA Olódùmarè yóò sì nu gbogbo omijé nù,
kúrò ní ojú gbogbo wọn;
Òun yóò sì mú ẹ̀gàn àwọn ènìyàn rẹ̀ kúrò
ní gbogbo ilẹ̀ ayé.
OLúWA ni ó ti sọ ọ́.