Isaiah 3:11

Isaiah 3:11 YCB

Ègbé ni fún ènìyàn búburú! Ìparun wà lórí i wọn A ó sì san èrè iṣẹ́ tí ọwọ́ wọn ti ṣe fún wọn.