Isaiah 39:8

Isaiah 39:8 YCB

Hesekiah wí fún Isaiah pé “Rere ni ọ̀rọ̀ OLúWA tí ìwọ sọ,” Nítorí ó rò nínú ara rẹ̀ pé, “Àlàáfíà àti òtítọ́ yóò wà ní ìgbà ayé tèmi.”