Isaiah 41:18

Isaiah 41:18 YCB

Èmi yóò mú kí odò kí ó sàn ní ibi gíga àti orísun omi ní àárín Àfonífojì. Èmi yóò sọ aṣálẹ̀ di adágún omi, àti ilẹ̀ tí ó gbẹ gidigidi di orísun omi.