Isaiah 43:19

Isaiah 43:19 YCB

Wò ó, Èmi ń ṣe ohun tuntun! Nísinsin yìí ó ti yọ sókè; àbí o kò rí i bí? Èmi ń ṣe ọ̀nà kan nínú aṣálẹ̀ àti odò nínú ilẹ̀ ṣíṣá.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Isaiah 43:19

Isaiah 43:19 - Wò ó, Èmi ń ṣe ohun tuntun!
Nísinsin yìí ó ti yọ sókè; àbí o kò rí i bí?
Èmi ń ṣe ọ̀nà kan nínú aṣálẹ̀
àti odò nínú ilẹ̀ ṣíṣá.