Isaiah 53:10

Isaiah 53:10 YCB

Síbẹ̀, ó wu OLúWA láti pa á lára àti láti mú kí ó jìyà, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé OLúWA fi ayé rẹ̀ fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, Òun yóò rí àrọ́mọdọ́mọ rẹ̀ àti ọjọ́ ayé rẹ̀ yóò pẹ́ títí, àti ète OLúWA ni yóò gbèrú ní ọwọ́ rẹ̀.