Isaiah 53:6

Isaiah 53:6 YCB

Gbogbo wa bí àgùntàn, ti ṣìnà lọ, ẹnìkọ̀ọ̀kan wa ti yà sí ọ̀nà ara rẹ̀; OLúWA sì ti gbé e ka orí ara rẹ̀ gbogbo àìṣedéédéé wa.