Isaiah 64:8

Isaiah 64:8 YCB

Síbẹ̀síbẹ̀, OLúWA, ìwọ ni Baba wa. Àwa ni amọ̀, ìwọ ni amọ̀kòkò; gbogbo wa jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.