Isaiah 65:23

Isaiah 65:23 YCB

Wọn kì yóò ṣe iṣẹ́ lásán, wọn kí yóò bímọ fún wàhálà; nítorí wọn yóò jẹ́ àwọn ènìyàn ti OLúWA bùkún fún, àwọn àti àwọn ìrandíran wọn pẹ̀lú wọn.