Jeremiah 10:23

Jeremiah 10:23 YCB

Èmi mọ̀ OLúWA wí pé ọ̀nà ènìyàn kì í ṣe ti ara rẹ̀, kì í ṣe fún ènìyàn láti tọ́ ìgbésẹ̀ ara rẹ̀.