Numeri 6:24-26

Numeri 6:24-26 YCB

“ ‘ “Kí OLúWA bùkún un yín Kí ó sì pa yín mọ́. Kí OLúWA kí o mú ojú rẹ̀ kí ó mọ́lẹ̀ sí i yín lára. Kí ó sì ṣàánú fún un yín. Kí OLúWA bojú wò yín; Kí ó sì fún un yín ní àlàáfíà.” ’