Numeri 9:23

Numeri 9:23 YCB

Nípa àṣẹ OLúWA ni wọ́n ń pa ibùdó wọn, nípa àṣẹ OLúWA náà sì ni wọ́n ń gbéra. Wọ́n gbọ́rọ̀ sí àṣẹ OLúWA ní ìbámu pẹ̀lú àṣẹ OLúWA láti ẹnu Mose.