Saamu 103:1

Saamu 103:1 YCB

Yin OLúWA, ìwọ ọkàn mi; àti gbogbo ohun tí ó wà nínú mi, yín orúkọ rẹ̀ mímọ́.