Saamu 84:11

Saamu 84:11 YCB

Nítorí OLúWA Ọlọ́run jẹ́ òòrùn àti asà; OLúWA fún ni ní ojúrere àti ọlá; kò sí ohun rere kan tí yóò fàsẹ́yìn fún àwọn tí ó rìn ní àìlábùkù.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 84:11