Saamu 95:1-2

Saamu 95:1-2 YCB

Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a kọ orin ayọ̀ sí OLúWA Ẹ jẹ́ kí a kígbe sókè sí àpáta ìgbàlà wa. Ẹ jẹ́ kí a wá sí iwájú rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́ kí a sì pòkìkí rẹ̀ pẹ̀lú ohun èlò orin àti ìyìn.