ORIN DAFIDI 95:1-2

ORIN DAFIDI 95:1-2 YCE

Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á kọrin sí OLUWA; ẹ jẹ́ kí á hó ìhó ayọ̀ sí Olùdáàbòbò ati ìgbàlà wa! Ẹ jẹ́ kí á wá siwaju rẹ̀ pẹlu ọpẹ́; ẹ jẹ́ kí á fi orin ìyìn hó ìhó ayọ̀ sí i.