Saamu 98:1

Saamu 98:1 YCB

Ẹ kọrin tuntun sí OLúWA, nítorí tí ó ṣe ohun ìyanu; ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ àti apá mímọ́ rẹ̀ o ṣe iṣẹ́ ìgbàlà fún un