Saamu 99:9

Saamu 99:9 YCB

Gbígbéga ni OLúWA Ọlọ́run wa kí a sìn ín ní òkè mímọ́ rẹ̀ nítorí OLúWA Ọlọ́run wa jẹ́ mímọ́.