Nitoriti kò mọ̀ ohun ti mbọ̀: tali o si le wi fun u bi yio ti ri?
Ẹnikẹ́ni kò mọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ọ̀la; ta ló lè sọ fún eniyan bí yóo ṣe ṣẹlẹ̀?
Níwọ́n ìgbà tí kò sí ẹni tí ó mọ ọjọ́-ọ̀lá, ta ni ó le è sọ fún un ohun tí ó ń bọ̀?
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò