Gal 5:24
Gal 5:24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Awọn ti iṣe ti Kristi Jesu ti kàn ara mọ agbelebu ti on ti ifẹ ati ifẹkufẹ rẹ̀.
Pín
Kà Gal 5Gal 5:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Àwọn tí í ṣe ti Kristi Jesu ti kan ara wọn mọ́ àgbélébùú pẹ̀lú ìfẹ́ àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ rẹ̀.
Pín
Kà Gal 5