Gẹn 22:15-16
Gẹn 22:15-16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Angeli OLUWA nì si kọ si Abrahamu lati ọrun wá lẹrinkeji, O si wipe, Emi tikalami ni mo fi bura, li OLUWA wi, nitori bi iwọ ti ṣe nkan yi, ti iwọ kò si dù mi li ọmọ rẹ, ọmọ rẹ na kanṣoṣo
Pín
Kà Gẹn 22