Ṣugbọn Oluwa mbẹ ninu tempili rẹ̀ mimọ́; jẹ ki gbogbo aiye pa rọ́rọ niwaju rẹ̀.
Ṣugbọn OLUWA ń bẹ ninu tẹmpili mímọ́ rẹ̀, kí gbogbo ayé parọ́rọ́ níwájú rẹ̀.
Ṣùgbọ́n OLúWA wà nínú tẹmpili mímọ́ rẹ̀; Ẹ jẹ́ kí gbogbo ayé parọ́rọ́ níwájú rẹ.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò