Isa 41:13
Isa 41:13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori emi Oluwa Ọlọrun rẹ yio di ọwọ́ ọ̀tun rẹ mu, emi o wi fun ọ pe, Má bẹ̀ru; emi o ràn ọ lọwọ.
Pín
Kà Isa 41Isa 41:13 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí èmi OLUWA Ọlọrun rẹ, ti di ọwọ́ ọ̀tún rẹ mú, èmi ni mo sọ fún ọ pé kí o má bẹ̀rù, n óo ràn ọ́ lọ́wọ́.”
Pín
Kà Isa 41