Joṣ 2:8-9
Joṣ 2:8-9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ki nwọn ki o tó dubulẹ, o gòke tọ̀ wọn lọ loke àja; O si wi fun awọn ọkunrin na pe, Emi mọ̀ pe OLUWA ti fun nyin ni ilẹ yi, ati pe ẹ̀ru nyin bà ni, ati pe ọkàn gbogbo awọn ara ilẹ yi di omi nitori nyin.
Pín
Kà Joṣ 2