Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Ẹk. Jer 5:19YBCV(Bibeli Mimọ)

Iwọ, Oluwa, li o wà lailai; itẹ́ rẹ lati iran de iran!

Ẹk. Jer 5:19BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ìwọ, OLúWA, jẹ ọba títí láé; ìjọba rẹ dúró láti ìran kan dé ìran mìíràn.

Ẹk. Jer 5:19YCE(Yoruba Bible)

Ṣugbọn ìwọ OLUWA ni ó jọba títí ayé, ìtẹ́ rẹ sì wà láti ìrandíran.