Owe 20:7
Owe 20:7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Olõtọ enia nrìn ninu iwa-titọ rẹ̀: ibukún si ni fun awọn ọmọ rẹ̀ lẹhin rẹ̀!
Pín
Kà Owe 20Owe 20:7 Yoruba Bible (YCE)
Olódodo a máa rìn ní ọ̀nà òtítọ́, ibukun ni fún àwọn ọmọ rẹ̀ tí wọ́n tẹ̀lé e.
Pín
Kà Owe 20