Owe 29:25
Owe 29:25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ibẹ̀ru enia ni imu ikẹkùn wá: ṣugbọn ẹnikẹni ti o gbẹkẹ rẹ̀ le Oluwa li a o gbe leke.
Pín
Kà Owe 29Owe 29:25 Yoruba Bible (YCE)
Ìbẹ̀rù eniyan a máa di ìdẹkùn fún eniyan, ṣugbọn ẹni bá gbẹ́kẹ̀lé OLUWA yóo wà láìléwu.
Pín
Kà Owe 29