ÌWÉ ÒWE 29:25

ÌWÉ ÒWE 29:25 YCE

Ìbẹ̀rù eniyan a máa di ìdẹkùn fún eniyan, ṣugbọn ẹni bá gbẹ́kẹ̀lé OLUWA yóo wà láìléwu.