Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 118:6YBCV(Bibeli Mimọ)
Oluwa mbẹ fun mi, emi kì yio bẹ̀ru; kili enia le ṣe si mi?
O. Daf 118:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLúWA ń bẹ fún èmi; èmi kì yóò bẹ̀rù. Kí ni ènìyàn lè ṣe sí mi?
O. Daf 118:6YCE(Yoruba Bible)
Nígbà tí OLUWA wà pẹlu mi, ẹ̀rù kò bà mí. Kí ni eniyan lè fi mí ṣe?