Ṣe àfiwé gbogbo èyà
O. Daf 133:1YBCV(Bibeli Mimọ)
KIYESI i, o ti dara o si ti dùn to fun awọn ará lati ma jumọ gbe ni irẹpọ̀.
O. Daf 133:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyèsi, ó ti dára ó sì ti dùn tó fún àwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ní ìrẹ́pọ̀.
O. Daf 133:1YCE(Yoruba Bible)
Ó dára, ó sì dùn pupọ, bí àwọn ará bá ń gbé pọ̀ ní ìrẹ́pọ̀.