Mo Yọ̀ǹda: Ìwé-Ìfọkànsìn Asínilórì Láti Ọwọ́ Àwọn Ẹlẹ́wọ̀nÀpẹrẹ
GBA ÌWÚRÍ NÍNÚ ÀPÒ ÌPAMỌ́ RẸ
"Nítorí pé ó dá mi lójú gbangba pé, kì í ṣe ikú tàbí ìyè, kì í ṣe àwọn angẹli tàbí ẹ̀mí èṣù, kì í ṣe ohun ìgbà ìsinsin yìí tàbí ohun tí ó ń bọ̀, tàbí àwọn agbára, tàbí òkè, tàbí ọ̀gbun, tàbí ohunkóhun nínú ìṣẹ̀dá ni yóò le yà wá kúrò nínú ìfẹ́ Ọlọ́run tí ó ń bẹ nínú Kristi Jesu, Olúwa wa."-Róòmù 8:38-39
Ṣe ó nifẹ si kika àwọn ìtàn ìwúrí iṣẹ́ Ọlọ́run lẹ́hìn ọgbà tàbí ìmúdàgbà sókè àwọn ẹbí nípa rírọ̀ mọ Ìhìn Rere? Fi orúkọ silẹ láti gba àwọn orísirísi ìwúrí àkọsílẹ̀, àwọn ìmúdójú ìwọ̀n ìgbìyànju ìwòyí, àti àwọn àkọsílẹ̀ miran nínú àpò ipamọ rẹ.
JẸ́ ONÍWÚRÍ ÈNÌYÀN:https://www.prisonfellowship.org/subscribe/
IDAGBASOKE Bọtini:Ọjọ_4 Ọjọ_4Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Bíbelì jẹ́ ìwé ìràpadà, òmìnira, àti ìrètí. Nínú àwọn ojú-ìwé rẹ̀ ni orírúirú ẹ̀dá ènìyàn, akínkanjú—àwọn oníròbìnùjẹ́-ọkàn l'ọ́kùnrin l'óbìnrin tí wọn ń wá ọ̀nà àbáyọ. Ní ọ̀nà kan tàbí òmínràn, wọ́n dàbìi àwọn àbọ̀dé elẹ́wọ̀n àná tàbí àwọn tí wọ́n ń ṣe ẹ̀wọ̀n lọ́wọ́lọ́wọ́ tí wọ́n kọ àwọn ìwé-ìfọkànsìn tí o fẹ́ kà báyìí. A ní èrò pé àwọn ohùn ìjọ làti inú àhámọ́ yìí yíó jẹ́ ìgbaniníyànjú àti ìwúrí fún ọ. Kí ọ̀rọ̀ ẹ̀rí wọn dá àwa náà s'ílẹ̀.
More