ỌGBỌ́NÀpẹrẹ

ỌGBỌ́N

Ọjọ́ 3 nínú 3

Ọgbọ́n : Ohun ìjà Ìjagun

Ẹwà ọgbọ́n wà nínú òye. Ìmọ̀ láì sí òye lè yọrí sí àṣìlò. Jésù fi èyí hàn nígbà tí Ó kọjú àṣìlò ẹsẹ Bíbélì ti èṣù pẹ̀lú òye tó tọ́. Ọgbọ́n ní ìdàpọ̀ pẹ̀lú òye, ń ràn wá lọ́wọ́ láti gbé ìgbésẹ̀ tó yẹ ní àkókò tó yẹ (Òwe 4:7)

Níní òye ọ̀rọ̀ Ọlọ́run máa ń ràn wá lọ́wọ́ láti ṣe àmúlò rẹ̀ bí ó ti tọ́, gẹ́gẹ́ bí Jésù ti ṣe. Ọgbọ́n àti òye yìí ṣe pàtàkì láti ṣẹ́gun ọ̀tá àti gbígbé ìgbé ayé ìwà bí Ọlọ́run

Ó máa ń mú ìmúdárá síi bá bí a ti ń tọ ìtẹ́ Ọlọ́run lọ fún ìránlọ́wọ́ nígbà wàhálà àti ìdààmú ayé tí à ń kojú láì sí ìkìlọ̀

1 Samuel 17:45-47 (NIV): David said to the Philistine, “You come against me with sword and spear and javelin, but I come against you in the name of the Lord Almighty, the God of the armies of Israel, whom you have defied. This day the Lord will deliver you into my hands, and I’ll strike you down and cut off your head. This very day I will give the carcasses of the Philistine army to the birds and the wild animals, and the whole world will know that there is a God in Israel. All those gathered here will know that it is not by sword or spear that the Lord saves; for the battle is the Lord’s, and he will give all of you into our hands.”

1 Sámúẹ́lì 17:45-47 (NIV): Dáfídìsì wí fún Filístínì náà pé, ìwọ́ mú idà àti ọkọ̀, àti awà tọ̀ mí wá, ṣùgbọ́n èmi tọ̀ ọ́ wá lí orúkọ Olúwa àwon ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì tí ìwọ́ ti gàn. Lónìí yìí li Olúwa yíò fi ìwọ lé mi lọ́wọ́, èmi o pa ọ́, èmi ó sì ké orí rẹ kúrò lí ara rẹ, èmi ó sì fi òkú ogún Filísínì fún ẹiyẹ ojú ọ̀run lónì yìí, àti fún ẹranko ìgbẹ́, gbogbo ayé yíò sì mọ̀ pé, Ọlọ́run wà fún Ísírẹ́lì. Gbogbo ìjọ ènìà yíò sì mọ̀ dájú pé, Olúwa kò fi idà òn ọ̀kọ̀gba ni là: nítorí pé ogun náà ti Olúwa ni, yíò sì fi ọ́ lé wá lọ́wọ́.

Ìgboyà Dáfídì wá láti inú òye rẹ̀ nípa agbára tó wà nínú orúkọ Ọlọ́run. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó lo ọfà àti òkúta, ìgbàgbọ́ rẹ̀ kò sí nínú àwọn ohun èlò wọ̀nyí ṣùgbọ́n nínú agbára orúkọ Ọlọ́run, èyí tó ti fojú rí nígbà tí ó ń dáàbò bo àwọn àgùntàn bàbá rẹ̀. Nípa ṣíṣe àmúlò ìmọ̀ àti ìrírí yìí, Dáfídì ní ọgbọ́n fún ìdojúkọ rẹ̀.

Philippians 2:10-11 (NIV) says: "That at the name of Jesus every knee should bow, in heaven and on earth and under the earth, and every tongue acknowledge that Jesus Christ is Lord, to the glory of God the Father."

Fílípì 2:10-11 (NIV) wí pé : " Pé, lí orúkọ Jésù ni kí gbogbo eékún kí ó máa kúnlẹ̀, àwọn ẹni tí ń bẹ ní ọ̀run, àti àwọn ẹni tí ń bẹ ní ilẹ́, àti àwọn ẹni tí ń bẹ nísàlẹ̀ ilẹ̀, àti pé kí gbogbo ahọ́n kí ó máa jẹ́wọ́ pé, Jésù Krístì ni Olúwa, fún ògo Ọlọ́run Baba.

Àwọn ìṣe Dáfídì fi ìdí ẹsẹ yìí hàn. Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé láti inú májẹ̀mú tuntun, alàkalẹ̀ gbígbẹ́kẹ̀lé agbára Ọlọ́run mú ìṣẹ́gun wá fún un lórí Gòlíàtì àti òmìnira fún àwọn ènìyàn rẹ̀.

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

ỌGBỌ́N

Kìí ṣe pé ìgbé ayé onígbàgbọ́ ní ọ̀nà kan pàtó tí ó ń gbà ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí ó ti gba Krístì. Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé a jẹ́ ti Krístì, a ṣì wà nínú ayé yìí (Jòhánù 17:16). ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àlàkalẹ̀ nílò ìmúyàtọ̀ tí ó mú ìdọ́gba bá wíwà wa lójúkorojú nínú ayé pẹ̀lú ìdámọ̀ wa nípa ẹ̀mí. Bíi ẹ̀dá ti ẹ̀mí, a gbọ́dọ̀ ṣe bó ti tọ́.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Mount Zion Faith Ministry fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://mountzionfilm.org/