ÌdánilójúÀpẹrẹ
Ọlọ́run fẹ́ MỌ̀ bóyá a ti gbà ọ́ là àti bóyá èrò ìjọba ọ̀run ni ìwọ íṣe! Ìdánilójú rẹ yóò máa dàgbà nípa ṣíṣe àṣàrò nínú Ọ̀rọ̀ Rẹ̀. Àwọn ẹsẹ̀ Bíbélì wọ̀nyí, yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti fi gbogbo ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ sínú Ọlọ́run ní gbogbo ìgbà. Jẹ́kí ayé rẹ ní ìyípadà nípa kíkọ́ àkọ́sórí nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run!
Ìdánilójú yóò ti ìdí mímọ Ọlọ́run ní tímọ́tímọ́ wá. Ọ̀nà kan láti ṣe èyí ni láti kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní àkọ́sórí. Àwọn ẹsẹ̀ Bíbélì wọ̀nyí jẹ́ oríṣi 500+ látinú kókó ẹ̀kọ́ bíi 48+ nínú ètò àkọ́sórí Bíbélì látọwọ́ MemLok. MemLok kò le, ó rọrùn àti wípé ó kún fún ìgbádùn. Àwọn fọ́nrán ìtọ́ni yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ ní ìbẹ̀rẹ̀. Ó wà lóríi ẹ̀rọ alágbèká àti àwọn ohun-èlò Windows. MemLok
Nípa Ìpèsè yìí
Olórun fé jé kí o mò pé a tí gbà onlà àti pé ìwo yóò lọ sí òrun! Ìdánilójú rè ń dàgbà sí nípasẹ ìbápàdé pẹ̀lú Olórun àti ṣíṣe àsàrò nínú Ọ̀rọ̀ Rẹ̀. Àwọn ẹsẹ̀ tó tẹ̀lé, nígbà tí o bá há wọn sórí, lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti simi ni ìdánilójú nínú Ọlọ́run ní gbogbo ọjọ́ ayé rè. Jé kí ayé rẹ ní ìyípadà nípa híhá Àwọn Ìwé Mímó sórí! Fún ìlànà ekún rẹ́rẹ́ fún híhá Àwọn Ìwé Mímó sórí, lọ si MemLok.com
More