1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:10
Yoruba Bible
Nítorí n óo wà pẹlu rẹ. Kò sí ẹni tí yóo fọwọ́ kàn ọ́ láti ṣe ọ́ níbi. Nítorí mo ní eniyan pupọ ninu ìlú yìí.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:10
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:9
Ní alẹ́ ọjọ́ kan, Paulu rí ìran kan. Ninu ìran náà Oluwa sọ fún un pé, “Má bẹ̀rù, máa waasu, má dákẹ́.
Ṣàwárí ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 18:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò