1
HABAKUKU 3:17-18
Yoruba Bible
Bí igi ọ̀pọ̀tọ́ kò tilẹ̀ rúwé, tí àjàrà kò sì so, tí kò sí èso lórí igi olifi; tí àwọn irúgbìn kò sì so lóko, tí àwọn agbo aguntan run, tí kò sì sí mààlúù ninu agbo mọ́, sibẹsibẹ, n óo yọ̀ ninu OLUWA, n óo yọ̀ ninu Ọlọrun Olùgbàlà mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí HABAKUKU 3:17-18
2
HABAKUKU 3:19
Ọlọrun, OLUWA, ni agbára mi; Ó mú kí ẹsẹ̀ mi yá nílẹ̀ bíi ti àgbọ̀nrín, ó mú mi rìn lórí àwọn òkè gíga. (Sí ọ̀gá akọrin; pẹlu àwọn ohun èlò orin olókùn.)
Ṣàwárí HABAKUKU 3:19
3
HABAKUKU 3:2
OLUWA, mo ti gbọ́ òkìkí rẹ, mo sì bẹ̀rù iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. Gbogbo bí ò ó tíí ṣe tí à ń gbọ́; tún wá ṣe bẹ́ẹ̀ nígbà tiwa; sì ranti àánú ní àkókò ibinu rẹ.
Ṣàwárí HABAKUKU 3:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò