1
AISAYA 5:20
Yoruba Bible
Àwọn tí ń pe ibi ní ire gbé; tí wọn ń pe ire ní ibi! Àwọn tí wọn ń fi òkùnkùn ṣe ìmọ́lẹ̀, tí wọn sì fi ìmọ́lẹ̀ ṣe òkùnkùn! Tí wọ́n fi ìkorò ṣe adùn, tí wọ́n sì fi adùn ṣe ìkorò.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí AISAYA 5:20
2
AISAYA 5:21
Àwọn tí ó gbọ́n lójú ara wọn gbé; tí wọ́n ka ara wọn kún ẹni tí ó ní ìmọ̀!
Ṣàwárí AISAYA 5:21
3
AISAYA 5:13
Nítorí náà àwọn eniyan mi óo lọ sí oko ẹrú nítorí àìmòye wọn, ebi ni yóo pa àwọn ọlọ́lá wọn ní àpakú, òùngbẹ óo sì gbẹ ọpọlọpọ wọn.
Ṣàwárí AISAYA 5:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò