1
ÌWÉ ÒWE 21:21
Yoruba Bible
Ẹni tí ń lépa òdodo ati àánú yóo rí ìyè, òdodo, ati iyì.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 21:21
2
ÌWÉ ÒWE 21:5
Dájúdájú èrò ẹni tí ó ṣiṣẹ́ tọkàntọkàn yóo yọrí sí ọ̀pọ̀, ṣugbọn ẹni tí ó bá ń kánjú jù kò ní ní ànító.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 21:5
3
ÌWÉ ÒWE 21:23
Ẹni tí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́ pa ara rẹ̀ mọ́ kúrò ninu ìyọnu.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 21:23
4
ÌWÉ ÒWE 21:2
Gbogbo ọ̀nà eniyan ni ó dára lójú ara rẹ̀, ṣugbọn ọkàn ni OLUWA ń wò.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 21:2
5
ÌWÉ ÒWE 21:31
Eniyan a máa tọ́jú ẹṣin sílẹ̀ de ọjọ́ ogun, ṣugbọn OLUWA ló ni ìṣẹ́gun.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 21:31
6
ÌWÉ ÒWE 21:3
Kí eniyan ṣe òdodo ati ẹ̀tọ́, sàn ju ẹbọ lọ lójú OLUWA.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 21:3
7
ÌWÉ ÒWE 21:30
Kò sí ọgbọ́n, tabi òye, tabi ìmọ̀, tí ó lè dojú kọ OLUWA kí ó mókè.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 21:30
8
ÌWÉ ÒWE 21:13
Ẹni tí ó kọ etí dídi sí igbe talaka, òun náà yóo kígbe, ṣugbọn kò ní rí ẹni dá a lóhùn.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 21:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò