1
ÌWÉ ÒWE 20:22
Yoruba Bible
Má sọ pé o fẹ́ fi burúkú san burúkú, gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, yóo sì gbà ọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 20:22
2
ÌWÉ ÒWE 20:24
OLUWA ní ń tọ́ ìṣísẹ̀ ẹni, eniyan kò lè ní òye ọ̀nà ara rẹ̀.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 20:24
3
ÌWÉ ÒWE 20:27
Ẹ̀mí eniyan ni fìtílà OLUWA, tíí máa wá gbogbo kọ́lọ́fín inú rẹ̀ kiri.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 20:27
4
ÌWÉ ÒWE 20:5
Èrò ọkàn eniyan dàbí omi jíjìn, ẹni tí ó bá ní ìmọ̀ ló lè fà á jáde.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 20:5
5
ÌWÉ ÒWE 20:19
Ẹni tí ó ń ṣe òfófó káàkiri a máa tú ọpọlọpọ àṣírí, nítorí náà má ṣe bá ẹlẹ́jọ́ kẹ́gbẹ́.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 20:19
6
ÌWÉ ÒWE 20:3
Nǹkan iyì ni pé kí eniyan máa yẹra fún ìjà, ṣugbọn òmùgọ̀ eniyan níí máa ń jà.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 20:3
7
ÌWÉ ÒWE 20:7
Olódodo a máa rìn ní ọ̀nà òtítọ́, ibukun ni fún àwọn ọmọ rẹ̀ tí wọ́n tẹ̀lé e.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 20:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò