1
ÌWÉ ÒWE 19:21
Yoruba Bible
Ọpọlọpọ ni èrò tí ó wà lọ́kàn ọmọ eniyan, ṣugbọn ìfẹ́ OLUWA ni àṣẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 19:21
2
ÌWÉ ÒWE 19:17
Ẹni tí ó ṣe ojurere fún àwọn talaka, OLUWA ni ó ṣe é fún, OLUWA yóo sì san ẹ̀san rẹ̀ fún un.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 19:17
3
ÌWÉ ÒWE 19:11
Ọgbọ́n kì í jẹ́ kí ọlọ́gbọ́n yára bínú, ògo rẹ̀ sì níláti fojú fo ẹ̀ṣẹ̀ dá.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 19:11
4
ÌWÉ ÒWE 19:20
Gbọ́ ìmọ̀ràn kí o sì gba ẹ̀kọ́, kí o lè rí ọgbọ́n lò lẹ́yìn ọ̀la.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 19:20
5
ÌWÉ ÒWE 19:23
Ìbẹ̀rù OLUWA a máa mú ìyè wá, ẹni tí ó ní i yóo ní ìfọ̀kànbalẹ̀, ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú kan kò ní ṣẹlẹ̀ sí i.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 19:23
6
ÌWÉ ÒWE 19:8
Ẹni tí ó ní ọgbọ́n fẹ́ràn ara rẹ̀, ẹni tí ó bá sì ní òye, yóo ṣe rere.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 19:8
7
ÌWÉ ÒWE 19:18
Bá ọmọ rẹ wí nígbà tí ó sì lè gbọ́ ìbáwí, má sì ṣe wá ìparun rẹ̀.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 19:18
8
ÌWÉ ÒWE 19:9
Ẹlẹ́rìí èké kò ní lọ láìjìyà, ẹni tí ó ń pa irọ́ yóo parun.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 19:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò