1
ORIN DAFIDI 100:5
Yoruba Bible
Nítorí OLUWA ṣeun; ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae, òtítọ́ rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 100:5
2
ORIN DAFIDI 100:4
Ẹ wọ ẹnubodè rẹ̀ tẹ̀yin tọpẹ́, kí ẹ sì wọ inú àgbàlá rẹ̀ tẹ̀yin tìyìn. Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, kí ẹ sì máa yin orúkọ rẹ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 100:4
3
ORIN DAFIDI 100:2
Ẹ fi ayọ̀ sin OLUWA. Ẹ wá siwaju rẹ̀ pẹlu orin ayọ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 100:2
4
ORIN DAFIDI 100:3
Ẹ mọ̀ dájú pé OLUWA ni Ọlọrun, òun ló dá wa, òun ló ni wá; àwa ni eniyan rẹ̀, àwa sì ni agbo aguntan rẹ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 100:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò