1
ORIN DAFIDI 99:9
Yoruba Bible
Ẹ yin OLUWA, Ọlọrun wa, kí ẹ sì jọ́sìn níbi òkè mímọ́ rẹ̀; nítorí pé mímọ́ ni OLUWA Ọlọrun wa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 99:9
2
ORIN DAFIDI 99:1
OLUWA jọba, kí àwọn orílẹ̀-èdè wárìrì; ó gúnwà lórí àwọn kerubu; kí ilẹ̀ mì tìtì.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 99:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò