1
ORIN DAFIDI 101:3
Yoruba Bible
N kò ní gba nǹkan burúkú láyè níwájú mi. Mo kórìíra ìṣe àwọn tí wọ́n tàpá sí Ọlọrun. N kò sì ní bá wọn lọ́wọ́ sí nǹkankan.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 101:3
2
ORIN DAFIDI 101:2
N óo múra láti hu ìwà pípé pẹlu ọgbọ́n; nígbà wo ni o óo wá sọ́dọ̀ mi? N óo máa fi tọkàntọkàn rin ìrìn pípé ninu ilé mi.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 101:2
3
ORIN DAFIDI 101:6
N óo máa fi ojurere wo àwọn olóòótọ́ ní ilẹ̀ náà, kí wọ́n lè máa bá mi gbé; ẹni tí ó bá sì ń hu ìwà pípé ni yóo máa sìn mí.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 101:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò