1
ORIN DAFIDI 102:2
Yoruba Bible
Má yọwọ́ lọ́ràn mi lọ́jọ́ ìṣòro! Dẹtí sí adura mi; kí o sì tètè dá mi lóhùn nígbà tí mo bá ké pè ọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 102:2
2
ORIN DAFIDI 102:1
Gbọ́ adura mi, OLUWA; kí o sì jẹ́ kí igbe mi dé ọ̀dọ̀ rẹ.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 102:1
3
ORIN DAFIDI 102:12
Bẹ́ẹ̀ sì ni ìwọ OLUWA gúnwà títí lae, ọlá rẹ sì wà láti ìran dé ìran.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 102:12
4
ORIN DAFIDI 102:17
Yóo gbọ́ adura àwọn aláìní, kò sì ní kẹ́gàn ẹ̀bẹ̀ wọn.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 102:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò