1
ORIN SOLOMONI 6:3
Yoruba Bible
Olùfẹ́ mi ló ni mí, èmi ni mo sì ni olùfẹ́ mi. Láàrin òdòdó lílì, ni ó ti ń da ẹran rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN SOLOMONI 6:3
2
ORIN SOLOMONI 6:10
Ta ni ń yọ bọ̀ bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ yìí, tí ó mọ́ bí ọjọ́, tí ó lẹ́wà bí òṣùpá. Tí ó sì bani lẹ́rù, bí àwọn ọmọ ogun tí wọn dira ogun?
Ṣàwárí ORIN SOLOMONI 6:10
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò