1
II. Kor 3:17
Bibeli Mimọ
Njẹ Oluwa li Ẹmí na: nibiti Ẹmí Oluwa ba si wà, nibẹ̀ li omnira gbé wà.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí II. Kor 3:17
2
II. Kor 3:18
Ṣugbọn gbogbo wa nwò ogo Oluwa laisi iboju bi ẹnipe ninu awojiji, a si npawada si aworan kanna lati ogo de ogo, ani bi lati ọdọ Oluwa ti iṣe Ẹmí.
Ṣàwárí II. Kor 3:18
3
II. Kor 3:16
Ṣugbọn nigbati on o ba yipada si Oluwa, a o mu iboju na kuro.
Ṣàwárí II. Kor 3:16
4
II. Kor 3:5-6
Kì iṣe pe awa to fun ara wa lati ṣirò ohunkohun bi ẹnipe lati ọdọ awa tikarawa; ṣugbọn lati ọdọ Ọlọrun ni tito wa; Ẹniti o mu wa tó bi iranṣẹ majẹmu titun; kì iṣe ti iwe, bikoṣe ti ẹmí: nitori iwe a mã pani, ṣugbọn ẹmí a mã sọni di ãye.
Ṣàwárí II. Kor 3:5-6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò