1
Iṣe Apo 7:59-60
Bibeli Mimọ
Nwọn sọ Stefanu li okuta, o si nképe Oluwa wipe, Jesu Oluwa, gbà ẹmí mi. O si kunlẹ, o kigbe li ohùn rara pe, Oluwa, má kà ẹ̀ṣẹ yi si wọn li ọrùn. Nigbati o si wi eyi, o sùn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 7:59-60
2
Iṣe Apo 7:49
Ọrun ni itẹ́ mi, aiye si li apoti itisẹ mi: irú ile kili ẹnyin o kọ́ fun mi? li Oluwa wi; tabi ibo ni ibi isimi mi?
Ṣàwárí Iṣe Apo 7:49
3
Iṣe Apo 7:57-58
Nigbana ni nwọn kigbe li ohùn rara, nwọn si dì eti wọn, nwọn si fi ọkàn kan rọ́ lù u, Nwọn si wọ́ ọ sẹhin ode ilu, nwọn sọ ọ lí okuta: awọn ẹlẹri si fi aṣọ wọn lelẹ li ẹsẹ ọmọkunrin kan ti a npè ni Saulu.
Ṣàwárí Iṣe Apo 7:57-58
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò