1
Oni 10:10
Bibeli Mimọ
Bi irin ba kújú, ti on kò si pọn oju rẹ̀, njẹ ki on ki o fi agbara si i; ṣugbọn ère ọgbọ́n ni lati fi ọ̀na hàn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Oni 10:10
2
Oni 10:4
Bi ọkàn ijoye ba ru si ọ, máṣe fi ipò rẹ silẹ; nitoripe itũbá ama tù ẹ̀ṣẹ nla.
Ṣàwárí Oni 10:4
3
Oni 10:1
OKÚ eṣinṣin o mu ororo-ikunra alapolu bajẹ ki o ma run õrùn buburu: bẹ̃ni wère diẹ wuwo jù ọgbọ́n ati ọlá lọ.
Ṣàwárí Oni 10:1
4
Oni 10:12
Ọ̀rọ ẹnu ọlọgbọ̀n li ore-ọfẹ; ṣugbọn ète aṣiwère ni yio gbe ara rẹ̀ mì.
Ṣàwárí Oni 10:12
5
Oni 10:8
Ẹniti o wà iho ni yio bọ́ sinu rẹ̀; ati ẹniti o si njá ọgbà tútù, ejo yio si bù u ṣán.
Ṣàwárí Oni 10:8
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò