1
Hos 11:4
Bibeli Mimọ
YBCV
Mo fi okùn enia fà wọn, ati idè ifẹ: mo si ri si wọn bi awọn ti o mu ajàga kuro li ẹrẹkẹ wọn, mo si gbe onjẹ kalẹ niwaju wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Hos 11:4
2
Hos 11:1
NIGBATI Israeli wà li ọmọde, nigbana ni mo fẹ́ ẹ, mo si pè ọmọ mi lati Egipti jade wá.
Ṣàwárí Hos 11:1