1
O. Daf 10:17-18
Bibeli Mimọ
Oluwa, iwọ ti gbọ́ ifẹ onirẹlẹ: iwọ o mu ọkàn wọn duro, iwọ o dẹ eti rẹ si i. Lati ṣe idajọ alaini-baba ati ẹni-inilara, ki ọkunrin aiye ki o máṣe daiya-fo-ni mọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 10:17-18
2
O. Daf 10:14
Iwọ ti ri i; nitori iwọ nwò ìwa-ìka ati iwọsi, lati fi ọ̀ran na le ọwọ rẹ; talaka fi ara rẹ̀ le ọ lọwọ; iwọ li oluranlọwọ alaini-baba.
Ṣàwárí O. Daf 10:14
3
O. Daf 10:1
EṢE ti iwọ fi duro li òkere rere, Oluwa; ẽṣe ti iwọ fi fi ara pamọ́ ni igba ipọnju.
Ṣàwárí O. Daf 10:1
4
O. Daf 10:12
Dide, Oluwa; Ọlọrun, gbé ọwọ rẹ soke: máṣe gbagbe olupọnju.
Ṣàwárí O. Daf 10:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò